Igba 1

Kaabo si Zúme
Igbasile

Iwọ yoo ni anfani lati gba itọsọna kan lori oni oni nọmba kan fun igba yii, ṣugbọn jọwọ rii daju pe ọmọ ẹgbẹ kọọkan ti ẹgbẹ rẹ ni ẹda ti a tẹjade ti awọn ohun elo fun ojo iwaju.

Gba iwe Itosona

Adura egbe (5min)
Bere pelu adua, emi ijinle pelu irapada lai si emi mimo.

Wo ki o Soro (15min)
WO
Olohun lo arinrin eniyan n se nkan to rorun lato le ni ikolu nla. Wo fidio yi lati ro ise olorun.
SALAYE
Ti jesu ba pinnu pe ki awon omo leyin oun gboran. kini idi ti o fi ni awon omo leyin

Wo ki o Soro (15min)
WO
Wini an pe ni omo leyin
SALAYE
  1. Ti o ba ro nipa ile ijosin kan. kilo wa si o lokan
  2. Kini iyato larin aworan ati nkan ti an pe ni ile ijosin to rorun
  3. Ewo lo ro pe o rorun ju lati sodi pupo ati pe kini idi

Wo ki o Soro (15min)
WO
An min sinu, An min sita, A wa laye, Bee na ni Emi Mimi
SALAYE
  1. Kini awon ibara eni soro lati ko eko ati lati gbo ohun olohun
  2. Ie gbigbo ati idahun si oro olohun je gege bi mimi. kini idi

Feti Sile Ki o ka Pelu i
AKORO

Ka Bibeli

Gbigbo oro Olohun ni gbogbo igba je kokoro ninu ibasepo pelu re

Wa idi S.O.A.P.S. kika bibeli ninu iwe itonisona zume ati lati feti sile gbo oro re

Feti Sile Ki o ka Pelu i
AKORO

Egbe Isiro

Bibeli so fun wa pe, gbogbo yin te n tele jesu, ni ojo kan e o royin ise te se, ohun te so ati ohun te ro. ki egbe isiro o gbaradi

Wa egbe isiro ninu iwe itonisona zume, ki o si feti sile ko gbo.

Ilowo
YA KURO
Adehun sinu egbe meji tabi meta.
IPIN
Lo akoko yi lati sise isiro pelu ibere. Iwe Itonisona Zume.

ITESIWAJU

Ku oriire . o pari igba akoko!

Bi isale ni igbese lati fi gbiyanju igba mi.
GBORAN
Bbiyanju S.O.A.P.S. Bibeli kika larin bayi ati ipade to n bo.
IPIN
Bere lowo Olohun eni ti yio bere egbe isiro pelu lilo ohun tio ti ko.
GBADURA
Gbadura pe ki Olohun ran o lowo, ki o je onigboran si, ki o si pe ki o sise ninu aye re.
#ZumeProject
Ta aworan ni pa S.O.A.P.S. mi mo Bibeli ati lati pin ni arin awujo