Nipa Ikẹkọ Zúme
Zume lo awon ohun elo ayelujara.
Ilepa Zume je ise Agbese:
Itumo zume ni iwukara ni ede Giriki.
Zume lo awon ohun elo ayelujara.
Zume ni akojopo mewa, wakati meji fun ikokan.:
- Fidio ati adaro lati ran ijo re lowo nipa mimo ipile isiro opo.
- Ijiroro apapo lati ran ijo yin lowo, nipa riro nu si ikan ti won so
- Awon ise kekeke ti yio ma je ki e le lo nkan tie ko.
- Ipenija lati ran egbe eko agbara ati dagba ninu igba.
Bawo lo ti bere:
- Tio ba le wole, gbiyanju lati se.
- Pe awon ore.
- Seto igba ti eo pade pelu ore.
- Je o da o loju pe o le wole pelu ero ayelujara.
Iyan ranpe fun ipade alakoko:
- Iwe Akosile Zume.
- To ba wu o, o le te idaako awon elegbe re.
- So pirojenito pelu telifisan, ko gbogbo le ri akoonu.